Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ọmọ náà dàgbà, ó gbé e pada fún ọmọbinrin Farao, ó sì fi ṣe ọmọ, ó sọ ọ́ ní Mose, ó wí pé, “Nítorí pé láti inú omi ni mo ti fà á jáde.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:10 ni o tọ