Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 19:24 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA sì wí fún un pé, “Sọ̀kalẹ̀ lọ, kí o mú Aaroni gòkè wá, ṣugbọn má ṣe jẹ́ kí àwọn alufaa ati àwọn eniyan náà rọ́ wá sórí òkè níbi tí mo wà, kí n má baà jẹ wọ́n níyà.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 19

Wo Ẹkisodu 19:24 ni o tọ