Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 19:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Èéfín bo gbogbo òkè Sinai mọ́lẹ̀, nítorí pé ninu iná ni OLUWA ti sọ̀kalẹ̀ sórí rẹ̀, ọ̀wọ̀n èéfín rẹ̀ sì gòkè lọ bí ọ̀wọ̀n èéfín iná ìléru ńlá, gbogbo òkè náà sì mì tìtì.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 19

Wo Ẹkisodu 19:18 ni o tọ