Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 19:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Pààlà yípo òkè náà fún wọn, kí o sì kìlọ̀ fún wọn pé, kí wọ́n ṣọ́ra, kí wọ́n má ṣe gun òkè yìí, tabi fi ọwọ́ kan ẹsẹ̀ òkè náà. Ẹnikẹ́ni tí ó bá fi ọwọ́ kan òkè yìí, pípa ni n óo pa á.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 19

Wo Ẹkisodu 19:12 ni o tọ