Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 18:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí wọn máa ṣe onídàájọ́ fún àwọn eniyan náà nígbà gbogbo; àwọn ọ̀rọ̀ tí ó bá jẹ́ pataki pataki nìkan ni wọn yóo máa kó wá sí ọ̀dọ̀ rẹ, kí wọ́n máa parí àwọn ẹjọ́ kéékèèké láàrin ara wọn. Èyí yóo mú kí ó rọ̀ ọ́ lọ́rùn, wọn yóo sì máa bá ọ gbé ninu ẹrù náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 18

Wo Ẹkisodu 18:22 ni o tọ