Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 18:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹtiro bá rú ẹbọ sísun sí Ọlọrun. Aaroni ati àwọn àgbààgbà Israẹli sì wá sọ́dọ̀ Jẹtiro, láti bá a jẹun níwájú Ọlọrun.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 18

Wo Ẹkisodu 18:12 ni o tọ