Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 17:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua ṣe bí Mose ti pàṣẹ fún un, ó bá àwọn ará Amaleki jagun. Mose ati Aaroni ati Huri bá gun orí òkè lọ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 17

Wo Ẹkisodu 17:10 ni o tọ