Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 16:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn eniyan Israẹli rí i, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí bi ara wọn léèrè pé, “Kí nìyí?” Nítorí pé, wọn kò mọ ohun tíí ṣe.Mose bá dá wọn lóhùn pé, “Oúnjẹ tí OLUWA fún yín láti jẹ ni.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 16

Wo Ẹkisodu 16:15 ni o tọ