Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 16:12 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo ti gbọ́ kíkùn tí àwọn ọmọ Israẹli ń kùn, wí fún wọn pé, ‘Ní ìrọ̀lẹ́, ẹ óo máa jẹ ẹran, ní òwúrọ̀, ẹ óo máa jẹ burẹdi ní àjẹyó. Nígbà náà ni ẹ óo tó mọ̀ pé èmi ni OLUWA Ọlọrun yín.’ ”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 16

Wo Ẹkisodu 16:12 ni o tọ