Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 16:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí Aaroni ti ń bá gbogbo ìjọ eniyan Israẹli sọ̀rọ̀, wọ́n wo apá aṣálẹ̀, wọ́n sì rí i pé ògo OLUWA hàn ninu ìkùukùu.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 16

Wo Ẹkisodu 16:10 ni o tọ