Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 14:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Farao súnmọ́ àwọn ọmọ Israẹli, tí àwọn ọmọ Israẹli gbé ojú sókè tí wọ́n rí àwọn ará Ijipti tí wọn ń bọ̀ lẹ́yìn wọn; ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi. Wọ́n kígbe sí OLUWA;

Ka pipe ipin Ẹkisodu 14

Wo Ẹkisodu 14:10 ni o tọ