Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 14:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA bá rán Mose, ó ní,

2. “Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé kí wọ́n yipada, kí wọ́n sì pàgọ́ siwaju Pi Hahirotu, láàrin Migidoli ati Òkun Pupa, níwájú Baali Sefoni; ẹ pàgọ́ yín siwaju rẹ̀ lẹ́bàá òkun.

3. Nítorí Farao yóo wí pé, ‘Ilẹ̀ ti ká àwọn eniyan Israẹli mọ́, aṣálẹ̀ sì ti sé wọn mọ́.’

Ka pipe ipin Ẹkisodu 14