Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 13:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Láàrin ọjọ́ meje tí ẹ óo fi jẹ burẹdi tí kò ní ìwúkàrà, a kò gbọdọ̀ rí burẹdi tí ó ní ìwúkàrà lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni ninu yín, kò sì gbọdọ̀ sí ìwúkàrà ní gbogbo agbègbè yín.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 13

Wo Ẹkisodu 13:7 ni o tọ