Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 13:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Ọlọrun mú kí wọ́n gba ọ̀nà aṣálẹ̀, ní agbègbè Òkun Pupa, àwọn eniyan Israẹli sì jáde láti ilẹ̀ Ijipti pẹlu ìmúrasílẹ̀ ogun.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 13

Wo Ẹkisodu 13:18 ni o tọ