Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 13:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ iwájú bí àwọn ọmọkunrin yín bá bèèrè ìtumọ̀ ohun tí ẹ̀ ń ṣe lọ́wọ́ yín, ohun tí ẹ óo wí fún wọn ni pé, ‘Pẹlu ipá ni OLUWA fi mú wa jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti, níbi tí a ti wà ní ìgbèkùn rí.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 13

Wo Ẹkisodu 13:14 ni o tọ