Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 10:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose dáhùn pé, “Gbogbo wa ni à ń lọ, ati àgbà ati èwe; ati ọkunrin ati obinrin, ati gbogbo agbo mààlúù wa, ati gbogbo agbo ẹran wa, nítorí pé a níláti lọ ṣe àjọ̀dún kan fún OLUWA.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:9 ni o tọ