Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 10:26 BIBELI MIMỌ (BM)

A níláti kó àwọn ẹran ọ̀sìn wa lọ, a kò ní fi ohunkohun sílẹ̀ lẹ́yìn, nítorí pé ninu wọn ni a óo ti mú láti fi rúbọ sí OLUWA Ọlọrun wa; a kò sì tíì mọ ohun tí a óo fi rúbọ, àfi ìgbà tí a bá débẹ̀.”

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:26 ni o tọ