Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 10:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Eṣú bo gbogbo ilẹ̀ Ijipti, wọ́n sì bà sí gbogbo ilẹ̀. Wọ́n pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ tí ó jẹ́ pé irú rẹ̀ kò sí rí, irú rẹ̀ kò sì tún tíì ṣẹlẹ̀ mọ́ láti ìgbà náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:14 ni o tọ