Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 1:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Orúkọ àwọn ọmọ Israẹli tí wọ́n bá Jakọbu wá sí Ijipti nìwọ̀nyí, olukuluku pẹlu ìdílé rẹ̀:

2. Reubẹni, Simeoni, Lefi, Juda,

3. Isakari, Sebuluni, Bẹnjamini,

Ka pipe ipin Ẹkisodu 1