Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 9:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ mọ̀ dájú pé, kì í ṣe nítorí ìwà òdodo yín ni OLUWA Ọlọrun yín fi ń fun yín ní ilẹ̀ dáradára yìí, nítorí pé, olórí kunkun eniyan ni yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:6 ni o tọ