Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 9:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá gbé ère ọmọ mààlúù tí ẹ yá, tí ó jẹ́ ohun ẹ̀ṣẹ̀, mo dáná sun ún, mo lọ̀ ọ́ lúbúlúbú, mo sì dà á sinu odò tí ń ṣàn wá láti orí òkè.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:21 ni o tọ