Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 9:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo bá dọ̀bálẹ̀ gbalaja níwájú OLUWA bíi ti àkọ́kọ́, fún ogoji ọjọ́; n kò jẹ, bẹ́ẹ̀ ni n kò sì mu, nítorí gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ ti dá, tí ẹ ṣe ohun tí ó burú níwájú OLUWA, tí ẹ sì mú un bínú.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:18 ni o tọ