Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 9:10 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA fún mi ní àwọn tabili òkúta meji náà, tí Ọlọrun fúnrarẹ̀ fi ọwọ́ ara rẹ̀ kọ. Gbogbo ọ̀rọ̀ tí ó ba yín sọ láti ààrin iná, ní ọjọ́ tí ẹ péjọ sí ẹsẹ̀ òkè náà ni ó wà lára àwọn tabili náà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 9

Wo Diutaronomi 9:10 ni o tọ