Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 8:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ranti OLUWA Ọlọrun yín nítorí òun ni ó fun yín ní agbára láti di ọlọ́rọ̀, kí ó lè fìdí majẹmu tí ó fi ìbúra bá àwọn baba yín dá múlẹ̀, bí ó ti rí lónìí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 8

Wo Diutaronomi 8:18 ni o tọ