Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 8:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó mú yín la aṣálẹ̀ ńlá tí ó bani lẹ́rù já, aṣálẹ̀ tí ó kún fún ejò olóró ati àkeekèé, tí ilẹ̀ rẹ̀ gbẹ, tí kò sì sí omi, OLUWA tí ó mú omi jáde fun yín láti inú akọ òkúta,

Ka pipe ipin Diutaronomi 8

Wo Diutaronomi 8:15 ni o tọ