Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 7:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, ẹni mímọ́ ni ẹ jẹ́ fún OLUWA Ọlọrun yín, OLUWA Ọlọrun yín ti yàn yín, láàrin gbogbo àwọn eniyan tí wọ́n wà ní gbogbo ayé, pé kí ẹ jẹ́ ohun ìní fún òun.

Ka pipe ipin Diutaronomi 7

Wo Diutaronomi 7:6 ni o tọ