Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 7:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé, wọn óo yí àwọn ọmọ yín lọ́kàn pada, wọn kò ní jẹ́ kí wọ́n tẹ̀lé èmi OLUWA mọ́. Àwọn oriṣa ni wọn óo máa bọ, èmi OLUWA yóo bínú si yín nígbà náà, n óo sì pa yín run kíákíá.

Ka pipe ipin Diutaronomi 7

Wo Diutaronomi 7:4 ni o tọ