Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 7:10 BIBELI MIMỌ (BM)

a sì máa san ẹ̀san lojukooju fún àwọn tí wọ́n kórìíra rẹ̀. Yóo pa wọ́n run, kò ní dáwọ́ dúró láti má gba ẹ̀san lára gbogbo àwọn tí wọ́n kórìíra rẹ̀, yóo san ẹ̀san fún wọn ní ojúkoojú.

Ka pipe ipin Diutaronomi 7

Wo Diutaronomi 7:10 ni o tọ