Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 6:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ gbọdọ̀ máa ṣe ohun tí ó tọ́, ati ohun tí ó yẹ lójú OLUWA; kí ó lè dára fun yín, kí ẹ lè lọ gba ilẹ̀ dáradára tí OLUWA ti búra láti fún àwọn baba yín,

Ka pipe ipin Diutaronomi 6

Wo Diutaronomi 6:18 ni o tọ