Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:9 BIBELI MIMỌ (BM)

O kò gbọdọ̀ tẹríba fún wọn, bẹ́ẹ̀ ni o kò gbọdọ̀ sìn wọ́n, nítorí pé Ọlọrun tíí máa ń jowú ni èmi OLUWA Ọlọrun rẹ. Èmi a máa fi ìyà ẹ̀ṣẹ̀ baba jẹ ọmọ ati ọmọ ọmọ, títí dé ìran kẹta ati ìran kẹrin ninu àwọn tí wọ́n kórìíra mi.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:9 ni o tọ