Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Èmi ni mo dúró láàrin ẹ̀yin ati OLUWA nígbà náà, tí mo sì sọ ohun tí OLUWA wí fun yín; nítorí ẹ̀rù iná náà ń bà yín, ẹ kò sì gun òkè náà lọ.“OLUWA ní,

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:5 ni o tọ