Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo ọ̀nà tí OLUWA Ọlọrun yín là sílẹ̀ ni kí ẹ máa tọ̀, kí ẹ lè wà láàyè, kí ó lè dára fun yín, kí ẹ sì lè pẹ́ lórí ilẹ̀ tí ẹ óo gbà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:33 ni o tọ