Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo ti dára tó, bí wọ́n bá ní irú ẹ̀mí yìí nígbà gbogbo, kí wọ́n bẹ̀rù mi, kí wọ́n sì pa gbogbo òfin mi mọ́, kí ó lè dára fún wọn, ati fún àwọn ọmọ wọn títí lae.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:29 ni o tọ