Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:24 BIBELI MIMỌ (BM)

wọ́n ní, ‘OLUWA Ọlọrun wa ti fi títóbi ati ògo rẹ̀ hàn wá, a sì ti gbọ́ ohùn rẹ̀ láàrin iná. Lónìí ni a rí i tí Ọlọrun bá eniyan sọ̀rọ̀, tí olúwarẹ̀ sì tún wà láàyè.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:24 ni o tọ