Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 5:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose pe gbogbo àwọn ọmọ Israẹli jọ, ó wí fún wọn pé, “Ẹ̀yin ọmọ Israẹli, ẹ gbọ́ àwọn ìlànà ati àwọn òfin tí n óo kà fun yín lónìí; ẹ kọ́ wọn, kí ẹ sì rí i pé ẹ̀ ń tẹ̀lé wọn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 5

Wo Diutaronomi 5:1 ni o tọ