Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa pa wọ́n mọ́, kí ẹ sì máa tẹ̀lé wọn, wọn yóo sì sọ yín di ọlọ́gbọ́n ati olóye lójú àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn. Orílẹ̀-èdè tí ó bá gbọ́ nípa àwọn ìlànà ati òfin wọnyi yóo wí pé, dájúdájú ọlọ́gbọ́n ati amòye eniyan ni yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:6 ni o tọ