Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:49 BIBELI MIMỌ (BM)

ati gbogbo agbègbè Araba ní apá ìlà oòrùn odò Jọdani títí dé Òkun Araba, tí à ń pè ní Òkun Iyọ̀, tí ó wà ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè Pisiga.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:49 ni o tọ