Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:43 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ya Beseri sọ́tọ̀ fún ẹ̀yà Reubẹni ninu aṣálẹ̀ láàrin ilẹ̀ tí ó tẹ́jú. Ó ya Ramoti sọ́tọ̀ ní Gileadi, fún ẹ̀yà Gadi, ó sì ya Golani sọ́tọ̀ ní Baṣani, fún ẹ̀yà Manase.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:43 ni o tọ