Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó lé àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n pọ̀ jù yín lọ, tí wọ́n sì lágbára jù yín lọ kúrò fun yín, kí ó baà lè ko yín wọlé kí ó sì fun yín ní ilẹ̀ wọn, kí ẹ sì jogún rẹ̀ bí ó ti wà lónìí.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:38 ni o tọ