Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ óo sì máa bọ oriṣa tí a fi igi ati òkúta gbẹ́ níbẹ̀. Iṣẹ́ ọwọ́ eniyan ni àwọn oriṣa wọnyi; wọn kò lè gbọ́ràn, tabi kí wọn ríran; wọn kò lè jẹun, bẹ́ẹ̀ ni wọn kò lè gbóòórùn.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:28 ni o tọ