Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 4:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Lẹ́yìn náà, ẹ súnmọ́ òkè náà, nígbà tí ó ń jóná, tóbẹ́ẹ̀ tí ahọ́n iná náà fẹ́rẹ̀ kan ojú ọ̀run, tí òkùnkùn ati ìkùukùu bo òkè náà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 4

Wo Diutaronomi 4:11 ni o tọ