Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 34:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Joṣua ọmọ Nuni kún fún ọgbọ́n nítorí pé Mose ti gbé ọwọ́ rẹ̀ lé e, nítorí náà àwọn ọmọ Israẹli ń gbọ́ tirẹ̀, wọ́n sì ń ṣe gẹ́gẹ́ bí àṣẹ tí OLUWA pa fún Mose.

Ka pipe ipin Diutaronomi 34

Wo Diutaronomi 34:9 ni o tọ