Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 34:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA wí fún un pé, “Ilẹ̀ tí mo búra fún Abrahamu, ati fún Isaaki, ati fún Jakọbu pé, n óo fi fún àwọn arọmọdọmọ wọn nìyí, mo jẹ́ kí o rí i, ṣugbọn o kò ní dé ibẹ̀.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 34

Wo Diutaronomi 34:4 ni o tọ