Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 34:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose gbéra láti pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu, ó gun orí òkè Nebo lọ títí dé ṣóńṣó òkè Pisiga, tí ó wà ní òdìkejì Jẹriko. OLUWA sì fi gbogbo ilẹ̀ náà hàn án láti Gileadi lọ, títí dé Dani,

Ka pipe ipin Diutaronomi 34

Wo Diutaronomi 34:1 ni o tọ