Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa fò fún ayọ̀, ẹ̀yin ọmọ Israẹli,ta ló tún dàbí yín,ẹ̀yin orílẹ̀-èdè tí OLUWA tìkalárarẹ̀ gbàlà?OLUWA tìkalárarẹ̀ ni ààbò yín, ati idà yín,òun ní ń dáàbò bò yín, tí ó sì ń fun yín ní ìṣẹ́gun.Àwọn ọ̀tá yín ni yóo máa wá bẹ̀bẹ̀ fún àánú,ẹ óo sì máa tẹ àwọn pẹpẹ ìrúbọ wọn mọ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:29 ni o tọ