Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ibi tí ó dára jùlọ ninu ilẹ̀ náà ni wọ́n mú fún ara wọn,nítorí pé ibẹ̀ ni ìpín olórí ogun wà,ó wá sí ọ̀dọ̀ àwọn olórí àwọn eniyan náà,àtòun, àtàwọn eniyan náà sì ń pa àṣẹ OLUWA mọ́,wọn sì ń ṣe ìdájọ́ òdodo.”

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:21 ni o tọ