Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 33:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó súre fún ẹ̀yà Josẹfu pé:“Kí OLUWA rọ òjò ibukun sórí ilẹ̀ wọn,kí ó sì bu omi rin ín láti abẹ́ ilẹ̀ wá.

Ka pipe ipin Diutaronomi 33

Wo Diutaronomi 33:13 ni o tọ