Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:46 BIBELI MIMỌ (BM)

ó ní, “Ẹ fi gbogbo ọ̀rọ̀ tí mo ba yín sọ lónìí sọ́kàn, kí ẹ sì pa á láṣẹ fún àwọn ọmọ yín, kí wọ́n lè pa gbogbo òfin wọnyi mọ́ lẹ́sẹẹsẹ.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:46 ni o tọ