Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:41 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí mo bá pọ́n idà mi,tí ó ń kọ yànrànyànràn,n óo fà á yọ láti fi ṣe ẹ̀tọ́.N óo gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi,n óo sì jẹ àwọn tí wọ́n kórìíra mi níyà.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:41 ni o tọ