Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Diutaronomi 32:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣebí àwọn ni ẹ fún ní ọ̀rá ẹran ìrúbọ yín,àwọn ni ẹ sì rú ẹbọ ohun mímu yín sí?Kí wọ́n dìde, kí wọ́n ràn yín lọ́wọ́ nisinsinyii,kí wọ́n sì dáàbò bò yín.

Ka pipe ipin Diutaronomi 32

Wo Diutaronomi 32:38 ni o tọ